vi
Books
Owen Jones

Ìkẹtàlá Ti Megan

Ìkẹtàlá Ti Megan ni ọ̀wọ́ kejì nínú mẹ́tàlélógún ti Ipele Megan. Ó jẹ́ ọjọ́ ìbí Megan tí ó ní agbára nínú ẹ̀mí. Láti ṣe àjọyọ̀ rẹ̀ pé ó da ọ[dọ́, àwọn òbí rẹ̀ nṣe àpèjẹ nlá kan fún u. Tẹbí tọ̀rẹ́ ni wọ́n pè síbi ayẹyẹ nlá náà, níbi tí olùṣètò orin tí ó jẹ́ akọni rẹ̀, Jack Hammer yóò ti gbé àwọn orin jáde. Ó ndà á rò bóyá ẹnikẹ́ni fi ojú sọ Grrr, àléjò rẹ̀ nlá tíí ṣe ànjọ̀nnú Ẹkùn ará ilẹ̀ Siberia. Kò máa níi ́lọ́kàn láti pàdé àlejò kan tí ó rẹwà lọ́kùnrin. Ipele Ti Megan wà fún àwọn ènìyàn láìfi ti ọjọ́ orí ṣe tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ ti ẹ̀mí.
40 printed pages
Original publication
2021
Publisher
Tektime
Translator
Sola Agboola

Impressions

  👍
  👎
  💧
  🐼
  💤
  💩
  💀
  🙈
  🔮
  💡
  🎯
  💞
  🌴
  🚀
  😄

  How did you like the book?

  Sign in or Register
fb2epub
Drag & drop your files (not more than 5 at once)