vi
Books
Owen Jones

Òkú Ààrin-Gbùngbùn

Àdó ólóró buburu kan bú jáde ni ile ìtàjà nla kan ni Baghdad, ti o pa pupọ awọn olùrajà ati osisẹ, ti ọpọlọpọ si yarọ. Laipẹ, awọn ẹgbẹ bọmbà olupara-ẹni tuntun di awọn ẹniti awọn ọlọpa meje lagbàáyé nwákiri nitoripe wọn ti di ẹrùjẹjẹ fún ara ilu, ti kò ni i se pẹlu ẹsìn tabi òsèlú. Wọn pe awọn akọsẹmọsẹ ẹrọ ayárabiàsá ti ijọba Ṣháínà ati SAS ti Gẹẹsi lati sèrànwọ, sugbọn njẹ wọn yio le sàwári okùnfà bọmbù tó nsẹlẹ lemọlemọ ki ó tó di wipé ọwọ ara ilu kò ni ká wọn mọ?
244 printed pages
Copyright owner
Tektime
Original publication
2022
Publication year
2022
Publisher
Tektime
Translator
Samson Adeyekun
Have you already read it? How did you like it?
👍👎
fb2epub
Drag & drop your files (not more than 5 at once)